I. Tim 2:5
I. Tim 2:5 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí Ọlọrun kan ni ó wà, alárinà kan ni ó sì wà láàrin Ọlọrun ati eniyan; olúwarẹ̀ ni Kristi Jesu, tí òun náà jẹ́ eniyan
Pín
Kà I. Tim 2I. Tim 2:5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori Ọlọrun kan ni mbẹ, Onilaja kan pẹlu larin Ọlọrun ati enia, on papa enia, ani Kristi Jesu
Pín
Kà I. Tim 2I. Tim 2:5 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí Ọlọrun kan ni ó wà, alárinà kan ni ó sì wà láàrin Ọlọrun ati eniyan; olúwarẹ̀ ni Kristi Jesu, tí òun náà jẹ́ eniyan
Pín
Kà I. Tim 2