I. Tim 1:13
I. Tim 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Bí mo tilẹ̀ jẹ́ asọ̀rọ̀-òdì sí Ọlọ́run rí, àti onínúnibíni àti ìkà ènìyàn: ṣùgbọ́n mo rí àánú gbà, nítorí tí mo ṣe é nínú àìmọ̀ àti àìgbàgbọ́.
Pín
Kà I. Tim 1I. Tim 1:13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi mo tilẹ jẹ asọ ọ̀rọ-odì lẹkan rí, ati oninunibini, ati elewu enia: ṣugbọn mo ri ãnu gbà, nitoriti mo ṣe e li aimọ̀ ninu aigbagbọ.
Pín
Kà I. Tim 1