I. Tes 3:12
I. Tes 3:12 Yoruba Bible (YCE)
Kí Oluwa mú kí ìfẹ́ yín sí ara yín ati sí gbogbo eniyan kí ó pọ̀ sí i, kí ó sì túbọ̀ jinlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí tiwa ti rí si yín.
Pín
Kà I. Tes 3I. Tes 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
A sì béèrè pé, kí Ọlọ́run ràn yín lọ́wọ́ tó bẹ́ẹ̀ tí ìfẹ́ yín yóò fi gbòòrò tí yóò sì sàn kan olúkúlùkù yín. Èyí yóò jẹ́ àpẹẹrẹ gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ àwa náà ṣe sàn kan ẹ̀yin náà.
Pín
Kà I. Tes 3I. Tes 3:12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ki Oluwa si mã mu nyin bisi i, ki ẹ si mã pọ̀ ninu ifẹ si ọmọnikeji nyin, ati si gbogbo enia, gẹgẹ bi awa ti nṣe si nyin
Pín
Kà I. Tes 3