I. Tes 1:3
I. Tes 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
A ń rántí yin ni àìsimi nígbà gbogbo níwájú Ọlọ́run àti Baba nípa iṣẹ́ ìgbàgbọ́ yín, iṣẹ́ ìfẹ́ yín àti ìdúró ṣinṣin ìrètí yín nínú Jesu Kristi Olúwa wa.
Pín
Kà I. Tes 1I. Tes 1:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Li aisimi li awa nranti iṣẹ igbagbọ́ nyin ati lãla ifẹ ati sũru ireti nyin ninu Oluwa wa Jesu Kristi, niwaju Ọlọrun ati Baba wa
Pín
Kà I. Tes 1