I. Sam 3:19 - Compare All Versions
I. Sam 3:19 YBCV (Bibeli Mimọ)
Samueli ndagba, Oluwa si wà pẹlu rẹ̀, kò si jẹ ki ọkan ninu ọ̀rọ rẹ̀ wọnni bọ́ silẹ.
I. Sam 3:19 YCE (Yoruba Bible)
Samuẹli sì ń dàgbà, OLUWA wà pẹlu rẹ̀, ó sì ń mú kí gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀ máa ṣẹ.
Pín
I. Sam 3 YCEI. Sam 3:19 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLúWA wà pẹ̀lú Samuẹli bí ó ṣe ń dàgbà, kò sì jẹ́ kí ọ̀kan nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ kùnà.