I. Sam 20:17
I. Sam 20:17 Yoruba Bible (YCE)
Jonatani tún mú kí Dafidi ṣe ìbúra lẹ́ẹ̀kan sí i, pẹlu ìfẹ́ tí ó ní sí i. Nítorí pé, Jonatani fẹ́ràn rẹ̀ bí ó ti fẹ́ràn ẹ̀mí ara rẹ̀.
Pín
Kà I. Sam 20I. Sam 20:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Jonatani mú kí Dafidi tún ìbúra ṣe nítorí ìfẹ́ tí ó ní sí i, nítorí tí ó fẹ́ ẹ gẹ́gẹ́ bí ó ti fẹ́ràn ara rẹ̀.
Pín
Kà I. Sam 20I. Sam 20:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Jonatani si tun mu ki Dafidi ki o bura nitoriti o sa fẹ ẹ: o si fẹ ẹ bi o ti fẹ ẹmi ara rẹ̀.
Pín
Kà I. Sam 20I. Sam 20:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Jonatani si tun mu ki Dafidi ki o bura nitoriti o sa fẹ ẹ: o si fẹ ẹ bi o ti fẹ ẹmi ara rẹ̀.
Pín
Kà I. Sam 20