I. Sam 17:32
I. Sam 17:32 Yoruba Bible (YCE)
Dafidi sọ fún Saulu pé, “Ẹ má bẹ̀rù ọkunrin yìí; èmi, iranṣẹ rẹ óo lọ bá a jà.”
Pín
Kà I. Sam 17I. Sam 17:32 Bibeli Mimọ (YBCV)
Dafidi si wi fun Saulu pe, Ki aiya ki o máṣe fò ẹnikẹni nitori rẹ̀; iranṣẹ rẹ yio lọ, yio si ba Filistini yi jà.
Pín
Kà I. Sam 17