I. Sam 11:1
I. Sam 11:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
NAHAṢI ara Ammoni si goke wá, o si do ti Jabeṣi-Gileadi: gbogbo ọkunrin Jabeṣi si wi fun Nahaṣi, pe, Ba wa da majẹmu, awa o si ma sìn ọ.
Pín
Kà I. Sam 11NAHAṢI ara Ammoni si goke wá, o si do ti Jabeṣi-Gileadi: gbogbo ọkunrin Jabeṣi si wi fun Nahaṣi, pe, Ba wa da majẹmu, awa o si ma sìn ọ.