I. Pet 4:2 - Compare All Versions

I. Pet 4:2 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ki ẹnyin ki o máṣe fi ìgba aiye nyin iyokù wà ninu ara mọ́ si ifẹkufẹ enia, bikoṣe si ifẹ Ọlọrun.

I. Pet 4:2 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Kí ẹ̀yin má ṣe fi ìgbà ayé yín ìyókù wà nínú ara mọ́ sí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ènìyàn bí kò ṣe sí ìfẹ́ Ọlọ́run.

I. Pet 4:2 YCE (Yoruba Bible)

Má tún máa ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ẹ̀dá mọ́, ṣugbọn máa ṣe ìfẹ́ Ọlọrun ninu gbogbo ìgbé-ayé rẹ tí ó kù.