I. Pet 3:13-14
I. Pet 3:13-14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Tani yio si ṣe nyin ni ibi, bi ẹnyin ba jẹ onítara si ohun rere? Ṣugbọn bi ẹnyin ba jìya nitori ododo, alafia ni: ẹ máṣe bẹru wọn, ki ẹ má si ṣe kọminu
Pín
Kà I. Pet 3I. Pet 3:13-14 Yoruba Bible (YCE)
Ta ni lè ṣe yín ní ibi tí ẹ bá ní ìtara fún ohun tíí ṣe rere? Ṣugbọn bí ẹ bá tilẹ̀ jìyà nítorí òdodo, ẹ ṣe oríire. Ẹ má bẹ̀rù àwọn tí wọn ń jẹ yín níyà, kí ẹ má jẹ́ kí ọkàn yín dàrú.
Pín
Kà I. Pet 3