I. A. Ọba 3:14
I. A. Ọba 3:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi iwọ o ba si rìn ni ọ̀na mi lati pa aṣẹ ati ofin mi mọ, gẹgẹ bi Dafidi baba rẹ ti rìn, emi o si sún ọjọ rẹ siwaju.