I. Joh 4:21
I. Joh 4:21 Yoruba Bible (YCE)
Àṣẹ tí a rí gbà láti ọ̀dọ̀ Jesu Kristi ni pé ẹni tí ó bá fẹ́ràn Ọlọrun, kí ó fẹ́ràn arakunrin rẹ̀ pẹlu.
Pín
Kà I. Joh 4I. Joh 4:21 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ofin yi li awa si ri gbà lati ọwọ́ rẹ̀ wá, pe ẹniti o ba fẹran Ọlọrun ki o fẹran arakunrin rẹ̀ pẹlu.
Pín
Kà I. Joh 4