I. Joh 4:15
I. Joh 4:15 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹnikẹni ti o ba jẹwọ pe Jesu Ọmọ Ọlọrun ni, Ọlọrun ngbé inu rẹ̀, ati on ninu Ọlọrun.
Pín
Kà I. Joh 4I. Joh 4:15 Yoruba Bible (YCE)
Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́wọ́ pé Ọmọ Ọlọrun ni Jesu, Ọlọrun ń gbé inú rẹ̀, òun náà sì ń gbé inú Ọlọrun.
Pín
Kà I. Joh 4