I. Joh 2:22
I. Joh 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ta ni èké? Ẹni tí ó sẹ́ pé Jesu kì í ṣe Kristi. Eléyìí ni Aṣòdì sí Kristi: ẹni tí ó sẹ́ Baba àti Ọmọ.
Pín
Kà I. Joh 2I. Joh 2:22 Bibeli Mimọ (YBCV)
Tani eke, bikoṣe ẹniti o ba sẹ́ pe Jesu kì iṣe Kristi? Eleyi ni Aṣodisi-Kristi, ẹniti o ba sẹ́ Baba ati Ọmọ.
Pín
Kà I. Joh 2