I. Kor 15:25-26
I. Kor 15:25-26 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí ó níláti jọba títí Ọlọrun yóo fi fi gbogbo àwọn ọ̀tá sí ìkáwọ́ rẹ̀. Ikú ni ọ̀tá ìkẹyìn tí yóo parun.
Pín
Kà I. Kor 15I. Kor 15:25-26 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori on kò le ṣaima jọba titi yio fi fi gbogbo awọn ọta sabẹ ẹsẹ rẹ̀. Ikú ni ọtá ikẹhin ti a ó parun.
Pín
Kà I. Kor 15