I. Kor 15:19
I. Kor 15:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Bí ó bá ṣe pé kìkì ayé yìí nìkan ní àwa ní ìrètí nínú Kristi, àwa jásí òtòṣì jùlọ nínú gbogbo ènìyàn.
Pín
Kà I. Kor 15I. Kor 15:19 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi o ba ṣe pe ni kìki aiye yi nikan li awa ni ireti ninu Kristi, awa jasi òtoṣi jùlọ ninu gbogbo enia.
Pín
Kà I. Kor 15