I. Kor 13:4
I. Kor 13:4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ifẹ a mã mu suru, a si mã ṣeun; ifẹ kì iṣe ilara; ifẹ kì isọrọ igberaga, kì ifẹ̀
Pín
Kà I. Kor 13I. Kor 13:4 Yoruba Bible (YCE)
Ìfẹ́ a máa mú sùúrù, a máa ṣe oore. Ìfẹ́ kì í jowú, kì í ṣe ìgbéraga, bẹ́ẹ̀ ni kì í fọ́nnu.
Pín
Kà I. Kor 13