I. Kor 1:18
I. Kor 1:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitoripe wère li ọ̀rọ agbelebu si awọn ti o nṣegbé; ṣugbọn si awa ti a ngbalà, agbara Ọlọrun ni.
Pín
Kà I. Kor 1I. Kor 1:18 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí ọ̀rọ̀ agbelebu Kristi jẹ́ ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ lójú àwọn tí ń ṣègbé. Ṣugbọn lójú àwọn tí à ń gbà là, agbára Ọlọrun ni.
Pín
Kà I. Kor 1