I. Kro 23:5 - Compare All Versions

I. Kro 23:5 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ẹgbaji si jẹ adena: ẹgbaji si fi ohun-elo ti mo ṣe lati buyìn, yìn Oluwa.

I. Kro 23:5 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ẹgbàajì (4,000) ni kí ó jẹ́ olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà àti ẹgbàajì (4,000) ni kí o sì jẹ́ ẹni ti yóò máa yin OLúWA pẹ̀lú ohun èlò orin, mo ti ṣe èyí fún ìdí pàtàkì yìí.

I. Kro 23:5 YCE (Yoruba Bible)

kí ẹgbaaji (4,000) máa ṣọ́nà, kí ẹgbaaji (4,000) sì máa yin OLUWA pẹlu oríṣìíríṣìí ohun èlò orin tí ọba pèsè.