Sekariah 10:1

Sekariah 10:1 YCB

Ẹ béèrè òjò nígbà àrọ̀kúrò ni ọwọ́ OLúWA; OLúWA tí o dá mọ̀nàmọ́ná, tí ó sì fi ọ̀pọ̀ òjò fún ènìyàn, fún olúkúlùkù koríko ní pápá.