Ìfihàn 22:20

Ìfihàn 22:20 YCB

Ẹni tí ó jẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí wí pé, “Nítòótọ́ èmi ń bọ̀ kánkán.” Àmín, Máa bọ̀, Jesu Olúwa!