Saamu 98:9

Saamu 98:9 BMYO

ẹ jẹ́ kí wọn kọrin níwájú OLúWA, nítorí tí yóò wá ṣèdájọ́ ayé bẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè nínú òdodo àti àwọn ènìyàn ní àìṣègbè pẹ̀lú.