Saamu 105:4-5

Saamu 105:4-5 YCB

Wá OLúWA àti ipá rẹ̀; wa ojú rẹ̀ nígbà gbogbo. Rántí àwọn ìyanu tí ó ti ṣe, ìyanu rẹ̀, àti ìdájọ́ tí ó sọ