Saamu 103:17-18

Saamu 103:17-18 YCB

Ṣùgbọ́n láti ayérayé ni ìfẹ́ OLúWA ti wà pẹ̀lú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, àti òdodo rẹ̀ wà láti ọmọdọ́mọ Sí àwọn tí ó pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́ àti àwọn tí ó rántí òfin rẹ̀ láti ṣe wọ́n.