Òwe 3:5-10

Òwe 3:5-10 BMYO

Gbẹ́kẹ̀lé OLúWA pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ má ṣe sinmi lé òye ara à rẹ. Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ òun yóò sì máa tọ́ ipa ọ̀nà rẹ. Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ bẹ̀rù OLúWA kí o sì kórìíra ibi. Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ àti okun fún àwọn egungun rẹ. Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún OLúWA, pẹ̀lú àkọ́so oko rẹ, nígbà náà ni àká rẹ yóò kún àkúnya àgbá rẹ yóò kún àkúnwọ́sílẹ̀ fún wáìnì tuntun.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Òwe 3:5-10

Òwe 3:5-10 - Gbẹ́kẹ̀lé OLúWA pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ
má ṣe sinmi lé òye ara à rẹ.
Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ
òun yóò sì máa tọ́ ipa ọ̀nà rẹ.

Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ
bẹ̀rù OLúWA kí o sì kórìíra ibi.
Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ
àti okun fún àwọn egungun rẹ.

Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún OLúWA,
pẹ̀lú àkọ́so oko rẹ,
nígbà náà ni àká rẹ yóò kún àkúnya
àgbá rẹ yóò kún àkúnwọ́sílẹ̀ fún wáìnì tuntun.Òwe 3:5-10 - Gbẹ́kẹ̀lé OLúWA pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ
má ṣe sinmi lé òye ara à rẹ.
Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ
òun yóò sì máa tọ́ ipa ọ̀nà rẹ.

Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ
bẹ̀rù OLúWA kí o sì kórìíra ibi.
Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ
àti okun fún àwọn egungun rẹ.

Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún OLúWA,
pẹ̀lú àkọ́so oko rẹ,
nígbà náà ni àká rẹ yóò kún àkúnya
àgbá rẹ yóò kún àkúnwọ́sílẹ̀ fún wáìnì tuntun.Òwe 3:5-10 - Gbẹ́kẹ̀lé OLúWA pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ
má ṣe sinmi lé òye ara à rẹ.
Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ
òun yóò sì máa tọ́ ipa ọ̀nà rẹ.

Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ
bẹ̀rù OLúWA kí o sì kórìíra ibi.
Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ
àti okun fún àwọn egungun rẹ.

Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún OLúWA,
pẹ̀lú àkọ́so oko rẹ,
nígbà náà ni àká rẹ yóò kún àkúnya
àgbá rẹ yóò kún àkúnwọ́sílẹ̀ fún wáìnì tuntun.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Òwe 3:5-10