Numeri 11:1

Numeri 11:1 YCB

Àwọn ènìyàn ń ṣe àròyé nípa wàhálà wọn sí etí ìgbọ́ OLúWA. Ìbínú OLúWA sì ru sókè nígbà tí ó gbọ́ àròyé yìí, Nígbà náà ni iná jáde láti ọ̀dọ̀ OLúWA bọ́ sí àárín wọn, ó sì run àwọn tó wà ní òpin ibùdó.