Mika 7:7

Mika 7:7 BMYO

Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi ní ìwòye ní ìrètí sí OLúWA, èmi dúró de Ọlọ́run olùgbàlà mi; Ọlọ́run mi yóò sì tẹ́tí sí mi.