Matiu 25:13

Matiu 25:13 YCB

“Nítorí náà, ẹ máa ṣọ́nà. Nítorí pé ẹ̀yin kò mọ ọjọ́ tàbí wákàtí tí Ọmọ Ènìyàn yóò dé.

Àwọn fídíò fún Matiu 25:13