Matiu 24:44

Matiu 24:44 YCB

Nítorí náà, ẹ gbọdọ̀ wà ní ìmúrasílẹ̀, nítorí ní wákàtí àìròtẹ́lẹ̀ ni dídé Ọmọ Ènìyàn yóò jẹ́.

Àwọn fídíò fún Matiu 24:44