Matiu 20:34

Matiu 20:34 YCB

Àánú wọn sì ṣe Jesu, ó fi ọwọ́ kan ojú wọn. Lójúkan náà, wọ́n sì ríran, wọ́n sì ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

Àwọn fídíò fún Matiu 20:34