Matiu 1:6

Matiu 1:6 YCB

Jese ni baba Dafidi ọba. Dafidi ni baba Solomoni, ẹni tí ìyá rẹ̀ jẹ́ aya Uriah tẹ́lẹ̀ rí.

Àwọn fídíò fún Matiu 1:6