Matiu 1:23

Matiu 1:23 BMYO

“Wúńdíá kan yóò lóyún, yóò sì bí ọmọkùnrin kan, yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Emmanueli,” (èyí tí ó túmọ̀ sí “Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa”).

Àwọn fídíò fún Matiu 1:23

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Matiu 1:23