Jeremiah 20:13

Jeremiah 20:13 YCB

Kọrin sí OLúWA! Fi ìyìn fún OLúWA! Ó gba ẹ̀mí àwọn aláìní lọ́wọ́ àwọn ẹni búburú.