Gẹnẹsisi 39:2

Gẹnẹsisi 39:2 YCB

OLúWA sì wà pẹ̀lú Josẹfu, ó sì bùkún un, ó sì ń gbé ní ilé ọ̀gá rẹ̀ ará Ejibiti.