Gẹnẹsisi 29:31

Gẹnẹsisi 29:31 BMYO

Nígbà tí OLúWA sì ri pé, Jakọbu kò fẹ́ràn Lea, ó ṣí i ni inú ṣùgbọ́n Rakeli yàgàn.