Gẹnẹsisi 26:2

Gẹnẹsisi 26:2 BMYO

OLúWA sì fi ara han Isaaki, ó sì wí pé, “Má ṣe sọ̀kalẹ̀ lọ sí Ejibiti, jókòó ní ilẹ̀ tí èmi ó fún ọ.