OLúWA sì bi mí léèrè, “Ọmọ ènìyàn, ǹjẹ́ àwọn egungun wọ̀nyí lè yípadà di àwọn ènìyàn bí?” Èmi sì wí pé, “Ìwọ OLúWA Olódùmarè, ìwọ nìkan ni o lè dáhùn sí ìbéèrè yìí.” Nígbà náà ni ó wí fún mi pé, “Sọtẹ́lẹ̀ sí àwọn egungun kí ó sì sọ fún wọn pé, ‘Ẹ̀yin egungun gbígbẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ OLúWA! Èyí ni ohun tí OLúWA Olódùmarè wí fún àwọn egungun wọ̀nyí: Èmi yóò mú kí èémí wọ inú yín ẹ̀yin yóò sì wá di ààyè.
Kà Esekiẹli 37
Feti si Esekiẹli 37
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Esekiẹli 37:3-5
4 Ọjọ
Awọn Ere Awọn Nkan Nla Meji ti soju iṣẹlẹ ti ọkanlẹlo diẹ ninu Bibeli, ti o soju awọn ohun orisun ara Jesu ti a gbọdọ ni a gbẹ nipa lati wa ni Kristiani ti o le ṣe iṣẹlẹ ti o dara. Nitorina pe a le soju iṣẹlẹ ọlọgbo lati mọ bii o le kede awọn iṣeduro ti o yẹ lati gba lati gba iṣẹlẹ ni ẹjẹ rere rẹ."
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò