Eksodu 24:16

Eksodu 24:16 BMYO

Ògo OLúWA sì wà ní orí òkè Sinai. Ìkùùkuu bo orí òkè náà fún ọjọ́ mẹ́fà, ni ọjọ́ keje ni OLúWA kọ sí Mose láti inú ìkùùkuu náà wá.