Eksodu 13:14

Eksodu 13:14 YCB

“Yóò sí ṣe ní àwọn ọjọ́ tí ń bọ̀, ní ìgbà tí àwọn ọmọ yín yóò béèrè lọ́wọ́ yín ‘Kí ni èyí túmọ̀ sí?’ Kí ìwọ kí ó sọ fún wọn pé, ‘Pẹ̀lú ọwọ́ agbára ní OLúWA fi mú wa jáde kúrò ni ilẹ̀ Ejibiti, kúrò ní oko ẹrú.