Ìṣe àwọn Aposteli 5:20

Ìṣe àwọn Aposteli 5:20 BMYO

Ó sì wí pé “Ẹ lọ dúró nínú tẹmpili kí ẹ sì máa ṣọ́ ọ̀rọ̀ ìyè yìí ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ fún àwọn ènìyàn.”