1 Samuẹli 4:18

1 Samuẹli 4:18 YCB

Nígbà tí ó dárúkọ àpótí ẹ̀rí OLúWA, Eli sì ṣubú sẹ́yìn kúrò lórí àga ní ẹ̀gbẹ́ bodè, ọrùn rẹ̀ ṣẹ́, ó sì kú, nítorí tí ó jẹ́ arúgbó ọkùnrin, ó sì tóbi, ó ti darí àwọn Israẹli fún ogójì ọdún.