1 Samuẹli 12:22

1 Samuẹli 12:22 YCB

Nítorí orúkọ ńlá rẹ̀ OLúWA kì yóò kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀, nítorí tí inú OLúWA dùn láti fi yín ṣe ènìyàn rẹ̀.