O. Daf 132:4-5

O. Daf 132:4-5 YBCV

Emi kì yio fi orun fun oju mi, tabi õgbe fun ipenpeju mi, Titi emi o fi ri ibi fun Oluwa, ibujoko fun Alagbara Jakobu.