Mat 5:2-10

Mat 5:2-10 YBCV

O si yà ẹnu rẹ̀, o si kọ́ wọn, wipe: Alabukún-fun li awọn òtoṣi li ẹmí: nitori tiwọn ni ijọba ọrun. Alabukún-fun li awọn ẹniti nkãnu: nitoriti a ó tù wọn ninu. Alabukún-fun li awọn ọlọkàn-tutù: nitori nwọn o jogún aiye. Alabukún-fun li awọn ẹniti ebi npa ati ti ongbẹ ngbẹ sipa ododo: nitori nwọn ó yo. Alabukún-fun li awọn alãnu: nitori nwọn ó ri ãnu gbà. Alabukún-fun li awọn oninu-funfun: nitori nwọn ó ri Ọlọrun. Alabukún-fun li awọn onilaja: nitori ọmọ Ọlọrun ni a ó ma pè wọn. Alabukúnfun li awọn ẹniti a ṣe inunibini si nitori ododo: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.

Àwọn fídíò fún Mat 5:2-10

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Mat 5:2-10

Mat 5:2-10 - O si yà ẹnu rẹ̀, o si kọ́ wọn, wipe:


Alabukún-fun li awọn òtoṣi li ẹmí: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.
Alabukún-fun li awọn ẹniti nkãnu: nitoriti a ó tù wọn ninu.
Alabukún-fun li awọn ọlọkàn-tutù: nitori nwọn o jogún aiye.
Alabukún-fun li awọn ẹniti ebi npa ati ti ongbẹ ngbẹ sipa ododo: nitori nwọn ó yo.
Alabukún-fun li awọn alãnu: nitori nwọn ó ri ãnu gbà.
Alabukún-fun li awọn oninu-funfun: nitori nwọn ó ri Ọlọrun.
Alabukún-fun li awọn onilaja: nitori ọmọ Ọlọrun ni a ó ma pè wọn.
Alabukúnfun li awọn ẹniti a ṣe inunibini si nitori ododo: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.