Mat 14:16-18

Mat 14:16-18 YBCV

Jesu si wi fun wọn pe, Nwọn kò ni ilọ; ẹ fun wọn li onjẹ. Nwọn si wi fun u pe, Awa kò ni jù iṣu akara marun ati ẹja meji nihinyi. O si wipe, Ẹ mu wọn fun mi wá nihinyi.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ