Mat 14:16-17

Mat 14:16-17 YBCV

Jesu si wi fun wọn pe, Nwọn kò ni ilọ; ẹ fun wọn li onjẹ. Nwọn si wi fun u pe, Awa kò ni jù iṣu akara marun ati ẹja meji nihinyi.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ