Job 34:10-11

Job 34:10-11 YBCV

Njẹ nitorina, ẹ fetisilẹ si mi, ẹnyin enia amoye: odõdi fun Ọlọrun ti iba fi huwa buburu, ati fun Olodumare, ti yio fi ṣe aiṣedede! Nitoripe ẹsan iṣẹ enia ni yio san fun u, yio si mu olukuluku ki o ri gẹgẹ bi ipa-ọ̀na rẹ̀.