Gẹn 13:1-2

Gẹn 13:1-2 YBCV

ABRAMU si goke lati Egipti wá, on, ati aya rẹ̀, ati ohun gbogbo ti o ni, ati Loti pẹlu rẹ̀, si ìha gusu. Abramu si là gidigidi, li ẹran-ọ̀sin, ni fadaka, ati ni wurà.