Eks 23:2-3

Eks 23:2-3 YBCV

Iwọ kò gbọdọ tọ̀ ọ̀pọlọpọ enia lẹhin lati ṣe ibi, bẹ̃ni iwọ kò gbọdọ sọ̀rọ̀ li ọ̀ran ki o tẹ̀ si ọ̀pọ enia lati yi ẹjọ́ po. Bẹ̃ni iwọ kò gbọdọ gbè talaka li ẹjọ́ rẹ̀.