I. A. Ọba 17:22

I. A. Ọba 17:22 YBCV

Oluwa si gbọ́ ohùn Elijah; ẹmi ọmọde na si tun padà wá sinu rẹ̀, o si sọji.